Riba (bribe)

1 19
Avatar for Odusanwo12
2 years ago

Owo eyin ni won n pe ni RIBA

RIBA kuku lowo ti ko tona

Eyi ti mutumuwa n funra won

Ti won si n gba lowo ara won

Ti won ba fe gbona eburu gbohun eto

Akekoo to n sanwo eyin,Awako to n San RIBA,ati bebe lo.

Olopaa to n gba owo eyin,Adajo to n gbebi fun alare nitori owo,NEPA naa o gbeyin,Olori ilu ati asofin omo iya ni won,Onise ijoba naa darapo mo a won OBAYEJE won yii.Meloo ni a fe ka ninu eyin adepele?

RIBA o taye se rara,N se lo n baye je.

Riba gbigba,owo eyin ,kikun ile loda,sise owo (hand) kuduru,gbigba abetele omo iya niwon.

Ta wa ni agba ninu riba gbigba? E je ka jawo ninu apon ti ko yo.

0
$ 0.00

Comments

Bribery in the community nowadays is too rampant

$ 0.00
2 years ago