read.cash Log in
O@Odusanwo12

Riba (bribe) Owo eyin ni won n pe ni RIBA RIBA kuku lowo ti ko tona Eyi ti mutumuwa n funra won Ti won si n gba lowo ara won Ti won ba fe gbona eburu gbohun eto Akekoo to n sanwo eyin,Awako to n San RIBA,ati bebe lo. Olopaa to n gba owo eyin,Adajo to n gbebi fun alare nitori owo,NEPA naa o gbeyin,Olori ilu ati asofin omo iya ni won,Onise ijoba naa darapo mo a won OBAYEJE won yii.Meloo ni a fe ka ninu eyin adepele? RIBA o taye se rara,N se lo n baye je. Riba gbigba,owo eyin ,kikun ile loda,sise owo (hand) kuduru,gbigba abetele omo iya niwon. Ta wa ni agba ninu riba gbigba? E je ka jawo ninu apon ti ko yo.

1 comment

Log in to join in Reading is open to everyone. Replying needs an account.